Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

May 30, 2019
OHUN TUNTUN

Abala Tuntun—Ìrírí

Abala Tuntun—Ìrírí

Abala tuntun kan ti wà lórí ìkànnì jw.org báyìí tá à ń pè ní “Ìrírí.” Nínú abála yìí, o máa rí ọ̀wọ́ àwọn àpilẹ̀kọ “Bíbélì Máa Ń Yí Ìgbésí Ayé Àwọn Èèyàn Pa Dà” àtàwọn ìrírí tuntun pẹ̀lú àwọn tá a ti gbé jáde tẹ́lẹ̀ tó jẹ́ ti àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà.

Lórí ètò ìṣiṣẹ́ JW Library, àwọn ìrírí tá a ṣẹ̀ṣẹ̀ gbé jáde nìkan ló wà ní abala tuntun “Ìrírí.”

O lè rí abala “Ìrírí” yìí lórí ìkànnì wa tó o bá lọ sí “Nípa Wa,” o sì lè rí i lórí JW Library lábẹ́ “Ohun Tó Wà Lórí Ìkànnì.”