Ohun Tuntun Wo Ló Wà ní JW.ORG?
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Àwọn Nǹkan Tí Bíbélì Sọ̀rọ̀ Nípa Ẹ̀—Àwọ̀n Tí Wọ́n Fi Ń Pẹja Láyé Ìgbà TÍ Wọ́n Ń Kọ Bíbélì
Àpilẹ̀kọ yìí jẹ́ ká mọ̀ nípa nẹ́ẹ̀tì tí wọ́n fi ń pẹja nínú Bíbélì.
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé—June 2026
Bó ṣe wà nínú Gálátíà 4:24, àwọn májẹ̀mú méjì wo ni Pọ́ọ̀lù ń sọ̀rọ̀ nípa ẹ̀?
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
Gustavo Joseph: A Ti Ń Sin Jèhófà fún Nǹkan Bí Àádọ́rin Ọdún ní Cuba
Gustavo Joseph sọ bí nǹkan ṣe rí fún òun àti ìyàwó ẹ̀ nígbà tí wọ́n ń ṣe alábòójútó àyíká, nígbà tí wọ́n bímọ àti nígbà tí wọ́n sìn ní Bẹ́tẹ́lì.
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
June 2026
Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti August 10–September 6, 2026 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.
ÌWÉ ŃLÁ
2025 Ìròyìn Iṣẹ́ Ìsìn Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé
Wàá rí ìròyìn nípa iṣẹ́ ìwàásù tí àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣe kárí ayé láti September 2024 sí August 2025.
ÀWỌN ORIN WA MÍÌ
Màá Dúró De Jèhófà
Tí o ò bá jẹ́ kí àwọn ìṣòro ẹ gbà ẹ́ lọ́kàn, tó o sì ń ṣe àwọn ohun tó máa jẹ́ kígbàgbọ́ ẹ lágbára, ìyẹn á fi hàn pé ò ń dúró de Jèhófà.

