Àwọn Ohun Tó Jáde Láìpẹ́ Yìí
Ohun Méjìlá Tó Ń Mú Kí Ìdílé Láyọ̀
Tó o bá ń tẹ̀ lé àwọn ìlànà yìí, ìdílé rẹ á láyọ̀.
Awọ Ẹja Àbùùbùtán—Ta Ló Ṣiṣẹ́ Àrà Yìí?
Báwo ni awọ ẹja àbùùbùtán ṣe máa ń dáàbò bò ó lọ́wọ́ kòkòrò àrùn?
Bó O Ṣe Lè Ní Ìtẹ́lọ́rùn àti Ìfọ̀kànbalẹ̀
Wàá rí mẹ́rin lára àwọn ìlànà Bíbélì tó ń ran àwọn èèyàn lọ́wọ́ kí wọ́n lè máa láyọ̀, kí ọkàn wọn sì túbọ̀ balẹ̀.
Àwọn Obìnrin inú Bíbélì—Kí La Rí Kọ́ Lára Wọn?
Wo ìyàtọ̀ tó wà láàárín àwọn obìnrin rere tí Bíbélì mẹ́nu kàn àtàwọn obìnrin búburú tó ṣe ohun tí kò dáa.
Kí Ni Ìpadàbọ̀ Kristi?
Ǹjẹ́ a máa lè fojú rí i tó bá dé?
Kí Nìdí Tí Jésù Fi Kú?
Báwo ni ikú rẹ̀ ṣe ṣe wá láǹfààní gan-an?
Kí Ló Túmọ̀ Sí Láti ‘Nífẹ̀ẹ́ Àwọn Ọ̀tá Wa’?
Kò rọrùn láti fi ọ̀rọ̀ tó ṣe kedere, tó sì nítumọ̀ tí Jésù sọ sílò.
Ṣé Ìkórìíra Lè Dópin?
Ká tó lè borí ẹ̀tanú àti ìkórìíra, a gbọ́dọ̀ sapá gan-an láti mú un kúrò nínú ọkàn àti èrò wa. Wo ohun márùn-ún tá a lè ṣe láti gbógun ti ẹ̀tanú àti ìkórìíra.
Má Fìwà Jọ Àwọn Tó Mọ Tara Wọn Nìkan
Ọ̀pọ̀ èèyàn máa ń rò pé àwọn sàn ju àwọn mí ì lọ, wọ́n máa ń fẹ́ kí wọ́n fún wọn nípò pàtàkì láwùjọ, wọ́n sì máa ń rò pé ohun kan tọ́ sí àwọn. Wo àwọn ìlànà Bíbélì tó máa ràn ẹ́ lọ́wọ́ tí ò ní jẹ́ kó o nírú èrò yẹn.
Ìgbà wo ni òpin ayé máa dé?
Ṣé Bíbélì sọ ìgbà tó máa dé gan-an?
Ibo La Ti Lè Rí Òtítọ́?
Bíbélì sọ ìdáhùn tó jóòótọ́ nípa àwọn ìbéèrè pàtàkì tá a máa ń béèrè.