Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

JULY 15, 2022
ÌRÒYÌN KÁRÍ AYÉ

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2022 #5

Ìròyìn Látọ̀dọ̀ Ìgbìmọ̀ Olùdarí ti Ọdún 2022 #5

Ọ̀kan lára Ìgbìmọ̀ Olùdarí sọ̀rọ̀ nípa àwọn àṣeyọrí tá a ti ṣe láìpẹ́ yìí lẹ́nu iṣẹ́ ìtúmọ̀ èdè àti bí wọ́n ṣe dá wa láre nílé ẹjọ́. Wọ́n tún fọ̀rọ̀ wá àwọn ará wa kan lẹ́nu wò ká lè rí ohun tó ràn wọ́n lọ́wọ́ láti jẹ́ adúróṣinṣin láìka inúnibíni tí wọ́n dojú kọ ní Soviet Union.