Àwọn Ìsọfúnni Kéékèèké àti Àwọn Ohun Míì Tó Jọ Ọ́ Tí STREAM.JW.ORG Ń Lò
Oríṣiríṣi ìsọfúnni kéékèèké ló wà, iṣẹ́ wọn sì yàtọ̀ síra, àmọ́ gbogbo wọn ló máa jẹ́ kó o lè gbádùn ìkànnì yìí. Àpẹẹrẹ bá a ṣe ń lo àwọn ìsọfúnni kéékèèké àtàwọn ohun míì tó jọ ọ́ ló wà nísàlẹ̀ yìí.
Orúkọ |
Ìdí |
Ìgbà a |
Oríṣi |
---|---|---|---|
sessionstream |
Ó máa jẹ́ ká mọ àwọn tó lẹ́tọ̀ọ́ láti wọlé sórí ìkànnì náà. |
Wákàtí márùn-ún |
Ìsọfúnni Tó Pọn Dandan |
XSRF-TOKEN |
Ó máa ń dáàbò bo ìkànnì lọ́wọ́ àwọn tó fẹ́ fi ayédèrú ọ̀nà wọlé síbẹ̀. |
Wákàtí márùn-ún |
Ìsọfúnni Tó Pọn Dandan |
_pk_id.${rand}.${rand}, pk_ref.${rand}.${rand}, _pk_ses.${rand}.${rand} |
A máa ń fi gba ìsọfúnni nípa bí ẹnì kan ṣe ń lo ìkànnì kan. A máa wá fi ìsọfúnni yìí ṣàkójọ báwọn èèyàn ṣe ń lo ìkànnì náà sí, àá sì fi mú kí ìkànnì náà sunwọ̀n sí i. Lára ìsọfúnni tá a máa ń gbà ni orúkọ tí ẹni náà fi ń wọlé sórí ìkànnì náà, irú browser tó ń lò, irú fóònù tàbí kọ̀ǹpútà tó ń lò, ibi tó ti ń lo ìkànnì náà, iye ìgbà tó ti lo ìkànnì náà tàbí apá kan níbẹ̀ àti bó ṣe máa ń pẹ́ tó láwọn apá ibì kan lórí ìkànnì náà. |
Ọdún kan |
Ìsọfúnni Tá A Fi Ń Ṣèwádìí |
ngStorage-language |
Ó máa ń jẹ́ kí ẹnì kan lè wọ ìkànnì náà tààràtà ní èdè tó ti yàn tẹ́lẹ̀ lórí https://stream.jw.org/. |
Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage) |
Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì |
pusherTransportEncrypted |
Ó máa jẹ́ ká lè ta ẹnì kan tó ń lo ìkànnì náà lólobó nípa ohun tó ń lọ lọ́wọ́lọ́wọ́. |
Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage) |
Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì |
branches |
Ó máa jẹ́ kí ẹnì kan tó lẹ́tọ̀ọ́ àtiṣe kòkáárí lórí ìkànnì náà lè ṣe àwọn nǹkan kan tó jẹ́ tàwọn ọ́fíìsì míì níbẹ̀. |
Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage) |
Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì |
member |
Ó máa jẹ́ ká lè tọ́jú ìsọfúnni nípa ẹni tó ń lo ìkànnì náà sínú browser ẹ̀, kó lè máa fara hàn ní abala àwọn tó ń lo ìkànnì náà, kó má bàa jẹ́ pé léraléra láá ṣẹ̀ṣẹ̀ máa wá ìsọfúnni náà. |
Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage) |
Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì |
ngStorage-username |
Ó máa jẹ́ kí ọrúkọ tí ẹnì kan fi wọlé sórí ìkànnì náà tún fara hàn ní abala Ìwọlé nígbà míì tó bá fẹ́ pa dà wọlé síbẹ̀. Àfi tí ẹnì kan bá yàn pé kí kọ̀ǹpútà máa ṣe bẹ́ẹ̀ fóun ló máa tó lè ṣe bẹ́ẹ̀. |
Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage) |
Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì |
ntStorage-token |
Ó máa jẹ́ kí ẹnì kan lè ṣí àwọn ètò orí ìkànnì tó ti ṣí tẹ́lẹ̀ nígbà tí wọ́n ké sí i pé kó wá ṣí i. |
Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage) |
Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì |
ntStorage-viewType |
Tí ẹnì kan bá ṣí abala kan lórí ìkànnì náà, ó máa jẹ́ kí kọ̀ǹpútà lè to ohun tó wà níbẹ̀ tẹ̀ léra tàbí kó tò ó sẹ́gbẹ̀ẹ́ ara wọn, ó sinmi lórí èyí tónítọ̀hún bá yàn tẹ́lẹ̀. |
Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage) |
Ìsọfúnni Tó Ṣe Pàtàkì |
Tún wo Àwọn Ìsọfúnni Kéékèèké àti Àwọn Ohun Míì Tó Jọ Ọ́ Tí Àwọn Ìkànnì Wa Ń Lò.
a Tá a bá sọ pé ìsọfúnni kan jẹ́ èyí tí “Kò lọ́jọ́ (á wà ní local storage)”, ohun tá à ń sọ ni pé orí ìkànnì wa kọ́ ni ìsọfúnni náà máa pa mọ́ sí, orí browser tí ẹni náà fi ń lọ sórí ìkànnì ni. Torí náà, irú àwọn ìsọfúnni yìí kì í lọ́jọ́ tó máa pa rẹ́, torí ó máa wà lórí browser yẹn títí, àfi tí ẹni náà bá pa àwọn ìsọfúnni tó wà lórí browser ẹ̀ rẹ́.