Àwọn Iṣẹ́ Ìkọ́lé
ÀWỌN IṢẸ́ ÌKỌ́LÉ
Fọ́tò Iṣẹ́ Ìkọ́lé ní Britain, Apá 9 (September 2019 sí February 2020)
Wàá rí bí wọ́n ṣe parí iṣẹ́ ìkọ́lé náà àti ìgbà tí ìdílé Bẹ́tẹ́lì bẹ̀rẹ̀ sí í lò ó.
ÀWỌN IṢẸ́ ÌKỌ́LÉ
Fọ́tò Iṣẹ́ Ìkọ́lé ní Britain, Apá 9 (September 2019 sí February 2020)
Wàá rí bí wọ́n ṣe parí iṣẹ́ ìkọ́lé náà àti ìgbà tí ìdílé Bẹ́tẹ́lì bẹ̀rẹ̀ sí í lò ó.
Àwọn Fọ́tò Iṣẹ́ Ìkọ́lé Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Wa ní Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, Apá 8 (March sí August 2019)
Àwọn òṣìṣẹ́ ń ṣiṣẹ́ àṣeparí nínú àwọn ilé gbígbé, ọ́fíìsì àtàwọn ilé tí àá ti máa tún àwọn nǹkan se. Wọ́n ń tún ojú ilẹ̀ ṣe nìṣó kó tó di pé wọ́n máa bẹ̀rẹ̀ síí lò ó.
Wọ́n Bá Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣiṣẹ́
Ẹ wá wo bá ṣe máa ń rí téèyàn bá ṣiṣẹ́ pẹ̀lú àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà lẹ́nu iṣẹ́ ìkọ́lé.
Fọ́tò Iṣẹ́ Ìkọ́lé ní Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì Apá 7 (September 2018 sí February 2019)
Wo ibi ti iṣẹ́ dé lorí ẹ̀ka ọ́fíìsì tuntun ti àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní ìlú Chelmsford, ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì.
Fọ́tò Iṣẹ́ Ìkọ́lé ní Britain, Apá 5 (September 2017 sí February 2018)
Àwọn èèyàn ti ń gbé méjì nínú àwọn ilé gbígbé mẹ́fà tí wọ́n kọ́. Wo ohun míì tí wọ́n tún gbé ṣe.
Fọ́tò Iṣẹ́ Ìkọ́lé ní Britain, Apá 6 (March sí August 2018)
Wo àwọn fọ́tò tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ yà níbi iṣẹ́ ìkọ́lé ẹ̀ka ọ́fíìsì tuntun tó ń lọ lọ́wọ́ ní Britain.
Fọ́tò Iṣẹ́ Ìkọ́lé ní Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, Apá 4 (March sí August 2017)
Iṣẹ́ ń lọ ní pẹrẹu lórí àwọn ọ́fíìsì àtàwọn ilé gbígbé tuntun ní Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì.
“Àwọn Obìnrin Láyè Tiwọn Lẹ́nu Iṣẹ́ Ìkọ́lé”
Ó lè yà ẹ́ lẹ́nu tó o bá gbọ́ àwọn iṣẹ́ tí wọ́n mọ̀ ọ́n ṣe.
Àwọn Fọ́tò Iṣẹ́ Ìkọ́lé Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Wa ní Philippines, Apá 2 (June 2015 sí June 2016)
Lẹ́nu àìpẹ́ yìí, àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà lórílẹ̀-èdè parí àtúnṣe ńlá tí wọ́n ń ṣe sí àwọn ilé ẹ̀ka ọ́fíìsì wọn tó wà ní Quezon City. Wo bí iṣẹ́ náà ṣe lọ.
Àwọn Fọ́tò Iṣẹ́ Ìkọ́lé Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Wa ní Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, Apá 3 (September 2016 sí February 2017)
Iṣẹ́ ń lọ dáadáa níbi ẹ̀ka ọ́fíìsì tuntun táwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń kọ́ sí Britain.
Fọ́tò Oríléeṣẹ́ Wa Tuntun ní Warwick, Apá 7 (September 2016 sí February 2017)
Gbogbo ilé tó wà ní oríléeṣẹ́ wa ní Warwick la ti ń lò báyìí. Ní Àwọn Ọ́fíìsì àti Ilé Tó Wà fún Onírúurú Iṣẹ́, ó lé ní 250 èèyàn tó ṣiṣẹ́ lórí àwọn ìpàtẹ yìí látìbẹ̀rẹ̀ dé ìparí àtàwọn ohun ìṣẹ̀ǹbáyé tó wà nínú rẹ̀.
Àwọn Fọ́tò Iṣẹ́ Ìkọ́lé Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Wa ní Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, Apá 2 (September 2015 sí August 2016)
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó yọ̀ǹda ara wọn àtàwọn agbaṣẹ́ṣe ti ń ṣètò ilẹ̀ tí wọ́n máa kọ́ ẹ̀ka ọ́fíìsì náà sí àti ibi tí wọ́n máa kọ́lé tí wọ́n á máa kó irinṣẹ́ sí, táwọn òṣìṣẹ́ á sì máa gbé kí wọ́n tó ṣiṣẹ́ ìkọ́lé ńlá yìí tán.
Oríléeṣẹ́ Tuntun—Ohun Mánigbàgbé Nínú Ìtàn Wa
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń kọ́ oríléeṣẹ́ wọn tuntun lọ́wọ́ nílùú Warwick, ní New York. Ó dá wọn lójú pé Ọlọ́run wà lẹ́yìn wọn lẹ́nu iṣẹ́ pàtàkì tí wọ́n ń ṣe yìí.
Wọn Ò Pa Ẹran Igbó Lára Nílùú Chelmsford
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ní Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ti bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ ẹ̀ka ọ́fíìsì wọn tuntun sí tòsí ìlú Chelmsford. Kí ni wọ́n ń ṣe kí wọ́n má bàa pa ẹran igbó lára?
Fọ́tò Oríléeṣẹ́ Wa Tuntun ní Warwick, Apá 6 (March sí August 2016)
Àwọn oṣù tí wọ́n lò gbẹ̀yìn níbi iṣẹ́ ìkọ́lé tó ń lọ ní oríléeṣẹ́ àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà nílùú Warwick, ní New York.
Ohun Táwọn Onílé Sọ
Báwo ló ṣe rí lára àwọn onílé kan pé àwọn yá àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ní ilé?
Àwọn Ẹlẹ́rìí Ò Pa Àwọn Ẹran Igbó àti Àyíká Lára Nílùú Warwick
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ oríléeṣẹ́ wọn tuntun sí ìpínlẹ̀ New York. Kí ni wọ́n ń ṣe kí wọn má bàa pa àyíká lára?
Fọ́tò Oríléeṣẹ́ Wa Tuntun ní Warwick, Apá 5 (September 2015 sí February 2016)
Wọ́n ṣe iná sí Àwọn Ọ́fíìsì àti Ilé Tó Wà fún Onírúurú Iṣẹ́, wọ́n ṣe òrùlé tó máa ń jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ wọlé síbẹ̀, wọ́n tún to òkúta pẹlẹbẹ-pẹlẹbẹ sílẹ̀, wọ́n sì ṣe ìbòrí sí ojú ọ̀nà táwọn èèyàn á máa gbà.
Bọ́rọ̀ Ṣe Rí Lára Àwọn Tó Ń Bá Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ṣiṣẹ́ ní Warwick
Ìrírí wo làwọn òṣìṣẹ́ kan tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí àtàwọn tó ń wa bọ́ọ̀sì ní nígbà tí wọ́n ń bá àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣiṣẹ́ ìkọ́lé?
Àwọn Fọ́tò Iṣẹ́ Ìkọ́lé Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Wa ní Ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì, Apá 1 (January sí August 2015)
Wo bí iṣẹ́ ṣe ń lọ sí níbi tá a ti ń kọ́ ẹ̀ka ọ́fíìsì wa tuntun ti ilẹ̀ Gẹ̀ẹ́sì ní tòsí ìlú Chelmsford ní Essex.
Fọ́tò Oríléeṣẹ́ Wa Tuntun ní Warwick, Apá 4 (May sí August 2015)
Wọ́n parí iṣẹ́ lórí ògiri àti òrùlé ilé gbígbé kan àti àwọn afárá tó so àwọn ilé pọ̀, wọ́n sì ti bẹ̀rẹ̀ sí í tún ojú ilẹ̀ ṣe.
Àwọn Fọ́tò Iṣẹ́ Ìkọ́lé Ẹ̀ka Ọ́fíìsì Wa ní Philippines, Apá 1 (February 2014 sí May 2015)
Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ń kọ́ àwọn ilé tuntun sí ẹ̀ka ọ́fíìsì wa tó wà nílùú Quezon ní Philippines, a sì ń tún àwọn èyí tó ti wà níbẹ̀ tẹ́lẹ̀ ṣe.
Fọ́tò Orílé-Iṣẹ́ Wa Tuntun ní Warwick—Apá 3 (January sí April 2015)
Ní February, àwọn ẹgbẹ̀rún méjì ààbọ̀ [2,500] òṣìṣẹ́ ló wá ṣiṣẹ́ ní Warwick lójoojúmọ́, àwọn òṣìṣẹ́ ọgọ́rùn-ún márùn ún [500] ló wá ń ṣiṣẹ́ lọ́sọ̀ọ̀sẹ̀. Wo bí iṣẹ́ náà ṣe ń tẹ̀ síwájú.
Ìlú Warwick Gbàlejò
Àwọn aráàlú Warwick ní ìpínlẹ̀ New York sọ̀rọ̀ nípa bó ṣe rí lára wọn láti bá àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà ṣiṣẹ́ ní oríléeṣẹ́ wa tuntun tá à ń kọ́.
Àwọn Gbọ̀ngàn Ìjọba Tá A Kọ́ fún Mílíọ̀nù Kan Àwọn Ẹlẹ́rìí
Kí ló ń mú kó wu àwọn tí kì í ṣe Ẹlẹ́rìí Jèhófà pé kí wọ́n rí Gbọ̀ngàn Ìjọba tuntun ládùúgbò wọn?
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Máa Kọ́ Orílé-Iṣẹ́ Tuntun
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà ti wà ní Brooklyn, nílùú New York láti ọdún 1909. Kí ló dé tí wọ́n fi fẹ́ kó lọ sí àríwá ìlú New York?