Ìsọfúnni Ṣókí—Tonga
- 104,000—Iye àwọn èèyàn
- 256—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 3—Iye àwọn ìjọ
- 495—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
A Rí “Péálì Kan Tó Níye Lórí Gan-An”
Kà nípa ohun tó mú kí Winston àti Pamela Payne láti Ọsirélíà gbádùn ìgbésí ayé wọn.