Ìsọfúnni Ṣókí—South Sudan
- 15,254,000—Iye àwọn èèyàn
- 2,319—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 35—Iye àwọn ìjọ
- 7,209—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
Ní tòsí Juba, South Sudan—Wọ́n ń wàásù fún ẹnì kan tó jẹ́ ẹ̀yà Mondari lédè Bari