Ìsọfúnni Ṣókí—Sierra Leone
- 8,642,000—Iye àwọn èèyàn
- 2,659—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 43—Iye àwọn ìjọ
- 3,539—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́
O Ri I Pe Ife Lo Mu Ki Nnkan Wa Letoleto Nile Ijeun Naa
To ba je pe láti awon odun 1990 si 1999 tabi leyin igba naa lo to bere si i lo si apejo agbegbe awa Elerii Jehofa, a wu e lori láti ko nipa awon ohun ta a maa n se lawon apejo ta a ti se ni opo odun seyin.