Ìsọfúnni Ṣókí—Guinea-Bissau
- 2,197,000—Iye àwọn èèyàn
- 215—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 4—Iye àwọn ìjọ
- 10,665—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
Kupul, Guinea-Bissau—Wọ́n ń bá àgbẹ̀ kan tó ń sọ èdè Portuguese Creole jíròrò látinu Bíbélì