Àwa Ẹlẹ́rìí Jèhófà Kárí Ayé

Dominica

Ìsọfúnni Ṣókí—Dominica

  • 73,000—Iye àwọn èèyàn
  • 397—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
  • 10—Iye àwọn ìjọ
  • 190—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún

ÌRÒYÌN

Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Túbọ̀ Ń Ṣètò Ìrànwọ́ Lẹ́yìn Ìjì Líle Tó Jà

Àwọn ẹ̀ka ọ́fíìsì àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà sọ̀rọ̀ nípa ìrànwọ́ tí wọ́n ń ṣe fáwọn tí ìjì líle Hurricane Irma àti Hurricane Maria ṣèpalára fún àti bí wọ́n ṣe ń fi ọ̀rọ̀ Ọlọ́run tù wọ́n nínú.