Ìsọfúnni Ṣókí—Colombia
- 51,673,000—Iye àwọn èèyàn
- 186,712—Iye àwọn òjíṣẹ́ tó ń kọ́ni lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì
- 2,271—Iye àwọn ìjọ
- 279—Iye èèyàn tí Ẹlẹ́rìí Jèhófà kan máa wàásù fún
ÌRÒYÌN
Àjọ Àwọn Atúmọ̀ Èdè Adití ní Kòlóńbíà Fún Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà Ní Àmì Ẹ̀yẹ
Àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà lórílẹ̀-èdè Kòlóńbíà gba àmì ẹ̀yẹ méjì torí pé àwọn èèyàn mọrírì bí wọ́n ṣe ń sapá láti ran àwọn tó ń sọ èdè adití lọ́wọ́ ní Kòlóńbíà.