Kàn sí Wa
Inú wa máa ń dùn láti ran àwọn tó fẹ́ mọ púpọ̀ sí i nípa Bíbélì lọ́wọ́. A tún máa ń láyọ̀ láti ran àwọn tó fẹ́ mọ̀ nípa iṣẹ́ tá à ń ṣe kárí ayé lọ́wọ́. Lo àwọn ìlujá tó wà nísàlẹ̀ yìí láti kàn sí àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà tó wà ládùúgbò rẹ.
Fi nọ́ńbà tó wà nísàlẹ̀ yìí pè wa tàbí kó o fi àdírẹ́sì ibẹ̀ kọ̀wé sí wa
Rota
Àkókò Iṣẹ́
Monday sí Friday
8:00 àárọ̀ sí 5:00 ìrọ̀lẹ́