Ilé Olódi Tí Wọ́n ti Dán Ìgbàgbọ́ Àwọn Èèyàn Jèhófà Wò
Ilé ńlá kan wà ní orílẹ̀-èdè Sípéènì tí wọ́n ti fi ọgọ́rọ̀ọ̀rún àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà sẹ́wọ̀n torí pé ẹ̀rí ọkàn wọn ò jẹ́ kí wọ́n ṣiṣẹ́ ológun.