KÁÀDÌ NÍPA ẸNÌ KAN NÍNÚ BÍBÉLÌ Nóà TẸ̀ Ẹ̣́ Wa káàdì yìí jáde, kó o sì kẹ́kọ̀ọ́ nípa Nóà. Gé e, ká a sí méjì kó o sì tọ́jú rẹ̀. Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Káàdì Eré Bíbélì O Tún Lè Wo ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ Nóà Ní Ìgbàgbọ́ Nínú Ọlọ́run Ọlọ́run pàṣẹ fún Nóà pé kó kọ́ áàkì kan kí ìdílé rẹ̀ má bàa pa run nígbà Ìkún Omi, ó sì ṣe bẹ́ẹ̀. Kí ni ìtàn Nóà àti Ìkún Omi kọ́ ẹ nípa ìdí tó fi yẹ ká nígbàgbọ́ nínú Ọlọ́run? ERÉ ALÁWÒRÁN Kí Lá Rí Kọ́ Lára Nóà? Wa eré yìí jáde, kó o sì tẹ̀ ẹ́, kí o sì wo bó o ṣe lè tẹ̀ lé àpẹẹrẹ ìgbọràn Nóà. Ẹ̀kọ́ Bíbélì Ọkọ̀ Nóà Kọ́ àwọn ọmọ rẹ nípa àwọn ẹranko tó wà nínú ọkọ̀ Nóà. ILÉ ÌṢỌ́ Ṣémù Rí Ìwà Ìbàjẹ́ Tó Wà Láyé Ṣáájú àti Lẹ́yìn Ìkún-Omi Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere. Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Nóà KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ Káàdì Eré Bíbélì Nípa Nóà Yorùbá Káàdì Eré Bíbélì Nípa Nóà https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502012437/univ/art/502012437_univ_sqr_xl.jpg