ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ Ta Lo Máa Fún Níṣìírí? TẸ̀ Ẹ̣́ Fún ẹnì kan níṣìírí kó lè máa sin Jèhófà, bí Ẹlikénà àti Hánà ṣe fún Sámúẹ́lì níṣìírí. Wà á jáde Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Eré Ìkẹ́kọ̀ọ́ O Tún Lè Wo ERÉ ALÁWÒRÁN Hánà Ran Sámúẹ́lì Lọ́wọ́ Kó Lè Sin Jèhófà Eré yìí máa ran àwọn ọmọ ọdún mẹ́ta sí mẹ́fà láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa ẹ̀bùn tí Hánà máa ń fún Sámúẹ́lì lọ́dọọdún. KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ Káàdì Bíbélì Nípa Hánà Ọlọ́run dáhùn àdúrà pàtó tí Hánà gbà. KỌ́ ỌMỌ RẸ Sámúẹ́lì Ń Bá A Lọ Láti Máa Ṣe Ohun tí Ó Dára Báwo lo ṣe lè fìwà jọ Sámúẹ́lì, kó o máa ṣe ohun tó tọ́, tí àwọn èèyàn bá tiẹ̀ ń ṣe ohun tí ò dáa? Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere. Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Ta Lo Máa Fún Níṣìírí? ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ FÚN ÀWỌN ỌMỌDÉ Ta Lo Máa Fún Níṣìírí? Yorùbá Ta Lo Máa Fún Níṣìírí? https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502016150/univ/art/502016150_univ_sqr_xl.jpg