ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ Àwọn Arákùnrin àti Arábìnrin Wa Ń Mú Ká Lókun TẸ̀ Ẹ̣́ Wo bí àwọn tó wà nínú ìdílé rẹ àti ìjọ rẹ ṣe lè mú kó o lókun. Wà á jáde Àwọn Àkòrí Tó Jọ Ọ́ Eré Ìkẹ́kọ̀ọ́ O Tún Lè Wo ÀWỌN ÀWÒRÁN ÌTÀN BÍBÉLÌ Jèhófà Fún Gídíónì Lókun Àwọn ọmọ ogun Gídíónì ṣẹ́gun àwọn ọmọ ogun Mídíánì, bó tiẹ̀ jẹ́ pé 450 ọmọ ogun Mídíánì ni ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn dojú kọ. ERÉ ALÁWÒRÁN Jèhófà Máa Ń Dáhùn Àdúrà Tó Ṣe Pàtó Àwọn ọmọ ọdún mẹ́fà sí mẹ́jọ máa gbádùn eré yìí, torí ó kọ́ wọn pé ó dáa kí wọ́n máa gbàdúrà tó ṣe pàtó. ERÉ ALÁWÒRÁN Áńgẹ́lì Kan Mú Kí Gídíónì Lókun Àwọn ọmọ ọdún mẹ́ta sí mẹ́fà la ṣe eré aláwòrán yìí fún kí wọ́n lè kùn ún. KÁÀDÌ ERÉ BÍBÉLÌ Káàdì Bíbélì Nípa Gídíónì Ẹ̀rù kọ́kọ́ ń bà á, àmọ́ ó wá di onígboyà. IṢẸ́ ÌJỌSÌN ÌDÍLÉ Bí Jèhófà Ṣe Ń Mú Ká Lókun Ẹ lo àwọn eré yìí pẹ̀lú Àwòrán Ìtàn Bíbélì nípa Gídíónì nígbà ìjọsìn ìdílé yín. Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ Eré Ọwọ́ fún Àwọn Ọmọdé Lo àwọn eré ọwọ́ tó gbádùn mọ́ni tó dá lórí Bíbélì yìí láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa ìwà rere. Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Àwọn Arákùnrin àti Arábìnrin Wa Ń Mú Ká Lókun ERÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ FÚN ÀWỌN ỌMỌDÉ Àwọn Arákùnrin àti Arábìnrin Wa Ń Mú Ká Lókun Yorùbá Àwọn Arákùnrin àti Arábìnrin Wa Ń Mú Ká Lókun https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502015226/univ/art/502015226_univ_sqr_xl.jpg