ERÉ ALÁWÒRÁN Dáfídì Wá ní Orúkọ Ọlọ́run TẸ̀ Ẹ̣́ To àwọn lẹ́tà inú orúkọ Ọlọ́run, kó o wá kọ́ ohun tí orúkọ rẹ̀ túmọ̀ sí. Wà á jáde O Tún Lè Wo ERÉ ALÁWÒRÁN Sólómọ́nì Hùwà Ọlọgbọ́n Wá ohun tó sọ nù nínú àwòrán yìí, so àmì tó-tò-tó pọ̀, kó o sì kùn ún. ERÉ ALÁWÒRÁN Ta Ló Yàn Láti Sin Jèhófà? Eré yìí máa ran àwọn ọmọ ọdún mẹ́fà sí mẹ́jọ kí wọ́n lè mọ àwọn èèyàn inú Bíbélì. ERÉ ALÁWÒRÁN Hánà Ran Sámúẹ́lì Lọ́wọ́ Kó Lè Sin Jèhófà Eré yìí máa ran àwọn ọmọ ọdún mẹ́ta sí mẹ́fà láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa ẹ̀bùn tí Hánà máa ń fún Sámúẹ́lì lọ́dọọdún. Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Dáfídì Wá ní Orúkọ Ọlọ́run ERÉ ALÁWÒRÁN Dáfídì Wá ní Orúkọ Ọlọ́run Yorùbá Dáfídì Wá ní Orúkọ Ọlọ́run https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/502016190/univ/art/502016190_univ_sqr_xl.jpg