Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

KÍ NI BÍBÉLÌ FI KỌ́NI GAN-AN? (ÌWÉ ÌKẸ́KỌ̀Ọ́)

Sún Mọ́ Ọlọ́run Nípasẹ̀ Àdúrà (Apá 2)

Orí kẹtàdínlógún ìwé Kí Ni Bíbélì Fi Kọ́ni Gan-an? ni ìwé ìkẹ́kọ̀ọ́ yìí dá lé

Wo ohun tí Bíbélì sọ nípa bó ṣe yẹ ká máa gbàdúrà àti ìgbà tó yẹ ká máa gbàdúrà.