Òótọ́ Ni Àwọn Ìtàn inú Bíbélì
Àwọn Ilẹ̀ àti Ibi Tí Bíbélì Sọ
Àkọsílẹ̀ Ayé Àtijọ́ Kan Jẹ́rìí Sí Ibi Tí Ẹ̀yà Ísírẹ́lì Kan Ti Wà
Àwọn àpáàdì tí wọ́n hú jáde nílùú Samáríà jẹ́rìí sí i pé òótọ́ làwọn ìtàn tó wà nínú Bíbélì.
Ìlú Nínéfè Pa Run
Nígbà tí Ásíríà di orílẹ̀-èdè tó lágbára jù lọ láyé, wòlíì Ọlọ́run sọ tẹ́lẹ̀ nípa ohun kan tí wọn ò retí.
Ǹjẹ́ O Mọ̀? —July 2015
Bíbélì sọ pé igbó kìjikìji pọ̀ ní àwọn ibì kan ní Ilẹ̀ Ìlérí. Kò sí ọ̀pọ̀ lára igi tó wà níbẹ̀ mọ́, ṣó wá lè jẹ́ pé ìgbà kan wà rí tí igbó kìjikìji pọ̀ níbẹ̀?
Ǹjẹ́ O Mọ̀?—April 2013
Kí nìdí tí Bíbélì fi pe ìlú Nínéfè ìgbàanì ní “ìlú ńlá ìtàjẹ̀sílẹ̀”? Kí nìdí tí àwọn Júù fi máa ń ṣe ìgbátí yí òrùlé ilé wọn ká?
Àwọn Èèyàn Inú Bíbélì
Ǹjẹ́ O Mọ̀?—March 2020
Yàtọ̀ sí ohun tí Bíbélì sọ, ẹ̀rí míì wo ló tún fi hàn pé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì jẹ́ ẹrú nílẹ̀ Íjíbítì?
Orúkọ Bíbélì Kan Tó Wà Lára Ìkòkò
Ní 2012, àwọn awalẹ̀pìtàn ṣàwárí àfọ́kù ìkòkò amọ̀ kan tó ti tó 3,000 ọdún. Àfọ́kù ìkòkò yìí ti wá di ìran àpẹ́wò fáwọn olùṣèwádìí. Kí ló ṣàrà ọ̀tọ̀ nípa ẹ̀?
Ìwádìí Àwọn Awalẹ̀pìtàn Jẹ́ Ká Rí I Pé Ọba Dáfídì Gbé Láyé Rí Lóòótọ́
Àwọn alárìíwísí kan sọ pé ìtàn àròsọ lásán ni ìtàn Ọba Dáfídì, pé àwọn èèyàn ló hùmọ̀ ẹ̀. Àmọ́, kí làwọn awalẹ̀pìtàn rí?
Ǹjẹ́ O Mọ̀?—February 2020
Kí ni ìwádìí táwọn awalẹ̀pìtàn ṣe jẹ́ ká mọ̀ nípa Bẹliṣásárì?
Ẹ̀rí Mí ì Látọ̀dọ̀ Àwọn Awalẹ̀pìtàn
O lè má mọ ẹni tó ń jẹ́ Táténáì, àmọ́ ohun táwọn awalẹ̀pìtàn rí fi hàn pé ó wà lóòótọ́.
Ṣé Jòhánù Arinibọmi Wà Lóòótọ́?
Òpìtàn ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní náà Josephus gbà pé Jòhánù Arinibọmi tí gbé ayé rí, torí náà, ó yẹ káwa náà gbà bẹ́ẹ̀.
Ṣé Jésù Wà Lóòótọ́?
Kí ni ìtàn àtijọ́ àti tòde òní sọ nípa kókó yìí?
Ǹjẹ́ Àkọsílẹ̀ Bíbélì Nípa Ìgbésí Ayé Jésù Péye?
Ṣàgbéyẹ̀wò àwọn nǹkan tó jóòótọ́ nípa àkọsílẹ̀ tó wà nínu ìwé Ìhìn Rere àtàwọn ìwé àfọwọ́kọ tó pẹ́ jù lọ.
Ìbátan Káyáfà Ni
Ohun tí wọ́n hú jáde nípa Míríámù jẹ́ ká mọ pé àwọn tí Bíbélì dárúkọ wọn gbé ayé lóòótọ́, a sì mọ ìdílé wọn.
Ǹjẹ́ O Mọ̀? —November 2015
Kí nìdí tí Jósẹ́fù fi fá irun rẹ̀ kó tó lọ rí Fáráò? Bíbélì sọ pé Gíríìkì ni bàbá Tímótì. Ṣé èyí wá túmọ̀ sí pé ilẹ̀ Gíríìsì ni wọ́n bí i sí?
Nje O Mo? —May 2015
Does archaeology support the Bible record? Igba wo ni awon kinniun ku tan ni awon agbegbe Isireli?
Ìtàn Bíbélì
Ṣé Ìtàn Àròsọ Lásán Ni Ìtàn Nóà àti Ìkún Omi?
Bíbélì sọ pé ìgbà kan wà tí Ọlọ́run mú kí ìkún omi ńlá kan ṣẹlẹ̀, kó lè fi pa àwọn èèyàn burúkú rún. Àwọn ẹ̀rí wo ló wà nínú Bíbélì tó jẹ́ ká gbà pé ọ̀dọ̀ Ọlọ́run ni Ìkún Omi náà ti wá lóòótọ́?
Ṣé “Ilé Gogoro Bábélì” Ni Èdè Wa Ti Bẹ̀rẹ̀?
Kí ni ilé Gogoro Bábélì? Níbo ni èdè àwa èèyàn ti ṣẹ̀ wá?
Ǹjẹ́ O Mọ̀?—June 2022
Ṣé àwọn ará Róòmù máa ń gbà kí wọ́n sin òkú ẹni tí wọ́n pa sórí òpó igi, irú bí wọ́n ṣe pa Jésù?
Àwòrán Tí Wọ́n Gbẹ́ Sára Ògiri ní Íjíbítì Àtijọ́ Ti Ohun Tí Bíbélì Sọ Lẹ́yìn
Kà nípa bí àwòrán kan tó wà ní Íjíbítì àtijọ́ ṣe jẹ́ ká túbọ̀ rí i pé òótọ́ lohun tó wà nínú Bíbélì.
Ṣé Ohun Tí Bíbélì Sọ Nípa Àwọn Júù Nígbèkùn Bábílónì Jóòótọ́?
Ṣé àwọn ọ̀jọ̀gbọ́n gbà pé ohun tí Ọlọ́run sọ nípa ìgbésí ayé àwọn Júù nígbèkùn Bábílónì ṣẹlẹ̀ lóòótọ́?
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé —November 2015
Kí ló fi hàn pé kò pẹ́ táwọn ọmọ Ísírẹ́lì dó ti ìlú Jẹ́ríkò àtijọ́ tí wọ́n fi ṣẹ́gun rẹ̀?
Ǹjẹ́ O Mọ̀?—October 2012
Ǹjẹ́ àwọn Kristẹni sá kúrò ní Jùdíà kí Jerúsálẹ́mù tó pa run lọ́dún 70 Sànmánì Kristẹni? Àwọn wo ni “àwọn ọmọ àwọn wòlíì”?
Nígbà Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì
Orin Kíkọ ní Ísírẹ́lì Àtijọ́
Báwo ni orin ti ṣe pàtàkì tó nígbà ayé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì?
Irú Ohun Ìrìnnà Tí Ìjòyè Etiópíà Lò
Irú ohun ìrìnnà wo ni ìjòyè Etiópíà wà nínú ẹ̀ nígbà tí Fílípì lọ bá a?
Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé—October 2023
Ṣé mánà àti àparò nìkan làwọn ọmọ Ísírẹ́lì jẹ nígbà tí wọ́n wà ní aginjù?
Ǹjẹ́ O Mọ̀?—June 2022
Nígbà ayé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, báwo ni wọ́n ṣe ń ka oṣù àti ọdún?
Èdìdì Ayé Àtijọ́—Kí Ni Wọ́n?
Kí nìdìí táwọn èdìdì ayé àtijọ́ fi ṣe pàtàkì? Báwo làwọn ọba àtàwọn alákòóso ṣe ń lò wọ́n?
‘Láti Inú Àwọn Òkè Ńlá Ni Ìwọ Yóò Ti Máa Wa Bàbà’
Ohun tí àwọn awalẹ̀pìtàn ṣàwárí lẹ́nu àìpẹ́ yìí jẹ́ ká mọ̀ nípa bí wọ́n ṣe lo bàbà láyé ìgbà tí wọ́n kọ Bíbélì.
Bí Wọ́n Ṣe Ń Lo Ohun Ìṣaralóge Láyé Ìgbà Tí Wọ́n Ń Kọ Bíbélì
Kí làwọn obìnrin máa ń lò láti fi gbé ẹwà wọn yọ ní ayé ìgbà tí wọ́n ń kọ Bíbélì?
Ǹjẹ́ O Mọ̀?—October 2017
Kí nìdí tí Jésù fi dẹ́bi fún àwọn tó ń búra?
Ǹjẹ́ O Mọ̀?—Ilé Ìṣọ́ No. 5 2017
Ṣé èébú ni bí Jésù ṣe fi àwọn tí kì í ṣe Júù wé “ajá kéékèèké”?
Ǹjẹ́ O Mọ̀? —June 2017
Kí nìdí tí Jésù fi pe àwọn oníṣòwò tó ń tajà nínú tẹ́ńpìlì ní “robbers”?
Ǹjẹ́ O Mọ̀?—October 2016
Báwo ni agbára táwọn Róòmù fún ilé ẹjọ́ àwọn Júù ní ọgọ́rùn-ún ọdún kìíní ṣe pọ̀ tó? Ṣé lóòótọ́ ni pé láyé àtijọ́ àwọn kan máa ń fún èpò sínú oko ẹlòmí ì?
Ǹjẹ́ O Mọ̀? —December 2015
Ṣé “láti gbogbo orílẹ̀-èdè àwọn tí ń bẹ lábẹ́ ọ̀run” ni àwọn Júù ti wá sí Jerúsálẹ́mù ní Pẹ́ńtíkọ́sì ọdún 33 Sànmánì Kristẹni? Ibo làwọn tó wá dé sí?
Nje O Mo? —March 2015
Anfaani wo ni apositeli Poolu ri ninu jije omo ibile Roomu? Bawo ni won se n sanwo ise fun awon oluso aguntan laye igba ti won n ko Bibeli?
Ǹjẹ́ O Mọ̀? —May 2014
Kí nìdí tí àwọn Júù fi sọ fún Pílátù pé kó ṣẹ́ ẹsẹ̀ Jésù? Ṣé Dáfídì tiẹ̀ lè fi kànnàkànnà lásán pa Gòláyátì?
Ǹjẹ́ O Mọ̀? —February 2014
Álóè wo ni álóè tí wọ́n máa ń lò láyé ìgbà tí wọ́n kọ Bíbélì? Irú àwọn ọrẹ ẹbọ wo ni àwọn àlùfáà máa ń gbà nínú Tẹ́ńpìlì?
Ǹjẹ́ O Mọ̀?—January 2014
Báwo ni wọ́n ṣe ń fi ọrẹ ṣètìlẹyìn nínú tẹ́ńpìlì nígbà ayé Jésù? Ṣé òpìtàn tí ọ̀rọ̀ rẹ̀ péye ni Lúùkù tó jẹ́ ọ̀kan lára àwọn tó kọ Bíbélì?