Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà​—Eré

Lo àwọn eré yìí láti ṣàlàyé ohun tó ṣẹlẹ̀ nínú ọ̀wọ́ fídíò Kẹ́kọ̀ọ́ Lára Àwọn Ọ̀rẹ́ Jèhófà, kó o sì jíròrò àwọn ẹ̀kọ́ inú ẹ̀ pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ.

Dèbórà

Kí lo lè kọ́ lára Dèbórà tó jẹ́ ọ̀rẹ́ Jèhófà?

Ébẹ́lì

Kí lo lè kọ́ lára Ébẹ́lì tó jẹ́ ọ̀rẹ́ Jèhófà?

Jeremáyà

Kí lo lè kọ́ lára Jeremáyà tó jẹ́ ọ̀rẹ́ Jèhófà?

Hananáyà, Míṣáẹ́lì, àti Asaráyà

Kí ló rí kọ́ lára Hananáyà, Míṣáẹ́lì, àti Asaráyà tí wọ́n jẹ́ ọ̀rẹ́ Jèhófà?

Máà bínú, kò sóhun tó jọ ohun tó ò ń wá.