Ìbẹ̀rẹ̀ Ìwé
“Kí ìwọ sì fi gbogbo ọkàn rẹ àti gbogbo ẹ̀mí rẹ àti gbogbo okun rẹ nífẹ̀ẹ́ Jèhófà Ọlọ́run rẹ. Kí ọ̀rọ̀ wọ̀nyí tí mo ń pa láṣẹ fún ọ lónìí sì wà ní ọkàn rẹ, kí ìwọ sì fi ìtẹnumọ́ gbìn wọ́n sínú àwọn ọmọ rẹ, kí o sì máa sọ̀rọ̀ nípa wọn nígbà tí o bá jókòó nínú ilé rẹ àti nígbà tí o bá ń rìn ní ojú ọ̀nà àti nígbà tí o bá dùbúlẹ̀ àti nígbà tí o bá dìde.”