Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà


Ṣé o gbádùn ohun tó o kọ́?

Ṣé o gbádùn ohun tó o kọ́?

Ṣé ó wù ẹ́ kó o kẹ́kọ̀ọ́ sí i látinú Bíbélì?

Èyí wulẹ̀ jẹ́ ìtọ́wò ohun tó o máa kọ́ nínú ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!​—Ìjíròrò Látinú Bíbélì.

Ìwé yìí kì í ṣe títà, a ò sì gba owó fún ẹ̀kọ́ Bíbélì yìí. Inú wa máa dùn láti kọ́ ẹ lẹ́kọ̀ọ́ ní àkókò tó o bá fẹ́ àti níbi tó bá rọ̀ ẹ́ lọ́rùn.

O máa kọ́ ọ̀pọ̀ nǹkan nínú ẹ̀kọ́ Bíbélì yìí. Lára wọn ni:

  • Ìdí tá a fi wà láyé

  • Bá a ṣe lè ní àlàáfíà gidi

  • Bí ìdílé ṣe lè láyọ̀

  • Àwọn nǹkan tí Bíbélì sọ pé ó máa ṣẹlẹ̀ lọ́jọ́ iwájú

Tó o bá fẹ́ ìwé yìí, tó o sì fẹ́ tẹ̀ síwájú nínú ẹ̀kọ́ Bíbélì yìí, jọ̀wọ́ sọ fún ọ̀kan lára àwọn Ẹlẹ́rìí Jèhófà, tàbí kó o lọ sí jw.org láti béèrè fún ẹ̀kọ́ Bíbélì.