Ẹmi Awọn Oku—Wọn Ha Le Ran ọ Lọwọ Tabi Pa Ọ Lara Bi? Wọn Ha wa Niti Gidi Bi?
Kí ni Bíbélì sọ nípa àwọn tó ti kú? Ṣé wọ́n lè ràn ọ́ lọ́wọ́ tàbí pa ọ lára?
Ọ̀rọ̀ Ìṣáájú
Ọ̀pọ̀ èèyàn gbà gbọ́ pé àwọn òkú máa ń lọ sí ilẹ̀ ẹ̀mí, ibẹ̀ ni wọ́n ti máa ń wo àwọn tó wà láyé, tí wọ́n sì ń dá sí ohun tó ń lọ. Ṣé òótọ́ ni?
Awọn Ẹmi Ko Gbe Ki Wọn si Kú Rí Lori Ilẹ Aye
Ọ̀rọ̀ tí Ọlọ́run sọ fún Ádámù ọkùnrin àkọ́kọ́ jẹ́ ká mọ ohun tó máa ń ṣẹlẹ̀ sáwọn tó bá ti kú.
Ẹgbẹẹgbẹrun Awọn Ẹda Ẹmi
Nínú àlá kan tí Ọlọ́run mú kí Dáníẹ́lì lá, ó rí ẹgbẹẹgbẹ̀rún àwọn ẹ̀dá ẹ̀mí.
Iṣọtẹ ni Ilẹ Akoso Ẹmi
Àwọn áńgẹ́lì kan di ọlọ̀tẹ̀, èyí sì yọrí sí wàhálà ńlá fún aráyé.
Awọn Ẹmi-eṣu Jẹ Panipani!
Àwọn ohun tí Bíbélì sọ àti àwọn ohun tó ń ṣẹlẹ̀ lóde òní fi hàn pé wọn ò lójú àánú, wọ́n sì burú gan-an.
Awọn Ẹmi-eṣu Fi Eke Sọ Pe Awọn Oku Walaaye
Àwọn Ẹ̀mí Èṣù ti ṣi ọ̀pọ̀ èèyàn lọ́nà, àmọ́ Bíbélì tú àṣírí wọn.
Awọn Ẹmi-eṣu Fun Iṣọtẹ Lodisi Ọlọrun Ni Iṣiri
Wọ́n máa ń fi ohun tí àwọn èèyàn ń rò ṣì wọ́n lọ́nà.
Ṣiṣẹsin Jehofa, Kii Ṣe Satani
Kí ló máa fi hàn pé ohun tó tọ́ lò ń ṣe?
Ọjọ-ọla Agbayanu Kan
Ìgbà díẹ̀ ló kù tí Sátánì àti àwọn ẹ̀mí èṣù rẹ̀ ò ní ṣi àwọn èèyàn lọ́nà mọ́. Jèhófà á wá bù kún aráyé.
Paradise Ilẹ-aye Naa
Báwo ni ayé ṣe máa rí lẹ́yìn tí Jèhófà bá tún gbogbo ohun tí Sátánì ti bà jẹ́ ṣe?