Ẹ̀kọ́ 4
Ẹ̀kọ́ 4
Òjò ń rọ̀.
Táyọ̀ ń sunkún pé:
“Mi ò lè jáde.
Kí ló dé tí òjò yìí ò dá?”
Ṣùgbọ́n lójijì!
Oòrùn yọ.
Òjò ti dá.
Inú Táyọ̀ dùn!
Ó sáré jáde, ó sì rí ohun kan tó yà á lẹ́nu.
Táyọ̀ sọ pé, “Mi ò mọ̀ pé òjò látọ̀dọ̀ Ọlọ́run ló ń mú kí òdòdó dàgbà!”
IṢẸ́ ÒBÍ
Ka ẹsẹ Bíbélì yìí fún ọmọ rẹ:
Ní kí ọmọ rẹ tọ́ka sí:
Fèrèsé Ẹyẹ Táyọ̀
Igi Òdòdó
Fara balẹ̀ wá àwọn nǹkan yìí.
Kòkòrò Ọkọ̀ òfuurufú
Bi ọmọ rẹ pé:
Kí nìdí tí Jèhófà fi dá òjò?
[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 10]
[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 10]
[Àwòrán tó wà ní ojú ìwé 11]