Ojú Ìwé Ọgbọ̀n-lé-méjì
Ǹjẹ́ èèyàn lè jẹ́ olóòótọ́ nínú ayé oníwà ìbàjẹ́ yìí?
WO OJÚ ÌWÉ 5.
Báwo ni Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ṣe ran agbo ilé kan tó ń ṣe ẹ̀sìn Híńdù lọ́wọ́?
WO OJÚ ÌWÉ 9 SÍ 11.
Ẹ̀kọ́ pàtàkì wo ni a lè rí kọ́ lára obìnrin olóòótọ́ náà Rúùtù?
WO OJÚ ÌWÉ 19 SÍ 24.
Báwo ni ọkùnrin kan tí ojú rẹ̀ ti ń rí màbo láti kékeré ṣe di ọkọ àti bàbá kan tó ń láyọ̀, tó sì ń bójú tó ìdílé rẹ̀ dáadáa?
WO OJÚ ÌWÉ 26 SÍ 27.