JÍ! No. 1 2020 | Bó O Ṣe Lè Ní Ìbàlẹ̀ Ọkàn
Àìbalẹ̀ ọkàn ń pọ̀ sí i. Àmọ́ ọ̀pọ̀ nǹkan wà tó o lè ṣe láti ní ìbàlẹ̀ ọkàn.
BÓ O ṢE LÈ NÍ ÌBÀLẸ̀ ỌKÀN
Kí Ló Ń Kó Ẹ Lọ́kàn Sókè?
Ọ̀pọ̀ nǹkan lo lè ṣe kí àìbalẹ̀ ọkàn má bàa ṣàkóbá fún ẹ.
BÓ O ṢE LÈ NÍ ÌBÀLẸ̀ ỌKÀN
Kí Ló Ń Fa Àìbalẹ̀ Ọkàn?
Wo àwọn ohun tó ń fa àìbalẹ̀ ọkàn kó o sì wo èyí tó kàn ẹ́ lára wọn.
BÓ O ṢE LÈ NÍ ÌBÀLẸ̀ ỌKÀN
Kí Ni Àìbalẹ̀ Ọkàn?
Àìbalẹ̀ ọkàn ti di apá kan ìgbésí ayé àwa èèyàn. Wo bí àpọ̀jù rẹ̀ ṣe lè ṣàkóbá fún ara rẹ.
BÓ O ṢE LÈ NÍ ÌBÀLẸ̀ ỌKÀN
Bó O Ṣe Lè Kojú Àìbalẹ̀ Ọkàn
Wo àwọn ìlànà mélòó kan tó lè jẹ́ kó o kojú àìbalẹ̀ ọkàn tàbí kó o dín in kù.
BÓ O ṢE LÈ NÍ ÌBÀLẸ̀ ỌKÀN
Ìgbà Kan Ń Bọ̀ Tí Ọkàn Gbogbo Èèyàn Máa Balẹ̀
A ò lágbára láti yanjú gbogbo ohun tó ń fa àìbalẹ̀ ọkàn. Àmọ́ Jèhófà lè yanjú ẹ̀.
“Ìbàlẹ̀ Ọkàn Ń Mú Kí Ara Lókun”
Ọ̀rọ̀ tó wà ní Òwe 14:30 jẹ́ ara ọ̀rọ̀ ọgbọ́n tó wúlò nígbà gbogbo tó wà nínú Bíbélì.