ILÉ ÌṢỌ́—Ẹ̀DÀ TÓ WÀ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ April 2025

Àwọn àpilẹ̀kọ tá a máa kẹ́kọ̀ọ́ láti June 9–July 13, 2025 ló wà nínú Ilé Ìṣọ́ yìí.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 14

“Ẹ Fúnra Yín Yan Ẹni Tí Ẹ Fẹ́ Máa Sìn”

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní June 9-15, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 15

“Sísúnmọ́ Ọlọ́run Dára” fún Wa!

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní June 16-22, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 16

A Máa Jàǹfààní Tá A Bá Sún Mọ́ Àwọn Ará!

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní June 23-29, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 17

Jèhófà Ò Ní Fi Wá Sílẹ̀ Láé

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní June 30–July 6, 2025.

ÀPILẸ̀KỌ FÚN ÌKẸ́KỌ̀Ọ́ 18

Ẹ̀yin Ọ̀dọ́kùnrin, Ẹ Fara Wé Máàkù àti Tímótì

A máa kẹ́kọ̀ọ́ àpilẹ̀kọ yìí ní July 7-13, 2025.

Bá A Ṣe Lè Túbọ̀ Jàǹfààní Látinú Àwọn Àwòrán inú Ìwé Wa

Ronú nípa bí àwọn àwòrán inú ìwé wa ṣe lè jẹ́ kó o rántí àwọn ẹ̀kọ́ pàtàkì inú ẹ̀.