Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

October 24-30

2 ÀWỌN ỌBA 1-2

October 24-30
  • Orin 79 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 53

  • Àwọn Nǹkan Táá Jẹ́ Kó O Gbádùn Ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!”: (15 min.) Ìjíròrò. Ní ṣókí, fọ̀rọ̀ wá ọ̀rọ̀ wò lẹ́nu akéde kan tó ń fi ìwé Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé! kọ́ ẹnì kan lẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì. Bi akéde náà pé: Àwọn nǹkan wo lò ń gbádùn bó o ṣe ń lo ìwé yìí? Báwo láwọn fídíò àtàwọn ìbéèrè tó ń múni ronú jinlẹ̀ tó wà níbẹ̀ ṣe ń mú kí ẹni náà túbọ̀ lóye ohun tó ń kọ́?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 24

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 66 àti Àdúrà