December 11-17
JÓÒBÙ 25-27
Orin 34 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Kò Dìgbà Tá A Bá Jẹ́ Ẹni Pípé Ká Tó Lè Jẹ́ Olóòótọ́”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
Job 26:14—Kí ni ìwọ̀nba nǹkan díẹ̀ tá a mọ̀ nípa ìṣẹ̀dá ń jẹ́ ká mọ̀ nípa Jèhófà? (w16.11 9 ¶3)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Job 25:1–26:14 (th ẹ̀kọ́ 12)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o lò. Ẹni náà sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 1)
Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Jẹ́ kí ẹni náà mọ bó ṣe lè rí ìsọfúnni nípa àwọn nǹkan tó nífẹ̀ẹ́ sí lórí ìkànnì jw.org. (th ẹ̀kọ́ 17)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 13 ọ̀rọ̀ ìbẹ̀rẹ̀ àti kókó 1-3 (th ẹ̀kọ́ 15)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Jẹ́ Olóòótọ́ Nínú Èrò Rẹ”: (5 min.) Ìjíròrò.
Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (10 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù December.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bt orí 3 ¶4-11
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 57 àti Àdúrà