November 22-28
ÀWỌN ONÍDÀÁJỌ́ 1-3
Orin 126 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Ìtàn Tó Ń Mórí Ẹni Wú Nípa Ọkùnrin Onígboyà Kan”: (10 min.)
Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)
Ond 2:10-12—Ìkìlọ̀ wo ló wà nínú ìtàn yìí? (w05 1/15 24 ¶7)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) Ond 3:12-31 (th ẹ̀kọ́ 5)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
“Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Jẹ́ Kí Jèhófà Ràn Ẹ́ Lọ́wọ́ Nípasẹ̀ Àdúrà”: (10 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò Jẹ́ Kí Iṣẹ́ Sísọni Di Ọmọ Ẹ̀yìn Máa Fún Ẹ Láyọ̀—Máa Lo Àwọn Nǹkan Tí Jèhófà Pèsè—Àdúrà.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lffi ọ̀rọ̀ ìbẹ̀rẹ̀ ní ẹ̀kọ́ 02 àti kókó 1-3 (th ẹ̀kọ́ 11)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Di Ọ̀rẹ́ Jèhófà—Máa Ṣe Dáadáa Lóde Ẹ̀rí: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ káwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, tó bá ṣeé ṣe pe àwọn ọmọdé bíi mélòó kan wá sórí pèpéle, kó o sì bi wọ́n ní ìbéèrè yìí: Báwo la ṣe lè múra sílẹ̀ fún iṣẹ́ ìwàásù? Báwo la ṣe lè múra lọ́nà tó bójú mu àti níwọ̀ntúnwọ̀nsì tá a bá ń lọ sóde ẹ̀rí? Báwo la ṣe lè máa hùwà lọ́nà tó bójú mu lóde ẹ̀rí?
“Bá A Ṣe Lè Darí Ìpàdé Iṣẹ́ Ìsìn Pápá Lọ́nà Tá Ṣe Àwọn Ará Láǹfààní”: (10 min.) Alábòójútó iṣẹ́ ìsìn ni kó bójú tó apá yìí. Jẹ́ káwọn ará sọ ìdí tó fi yẹ ká máa tètè dé sípàdé iṣẹ́ ìsìn pápá.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 16 ¶9-13 àti àpótí 16A
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 29 àti Àdúrà