ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
Jèhófà Fọgbọ́n Pín Ilẹ̀ Fáwọn Èèyàn Rẹ̀
Kèké ni Jèhófà lò láti fún àwọn èèyàn rẹ̀ nítọ̀ọ́ni, bóyá láti mọ ibi tí wọ́n máa pín fún ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan (Joṣ 18:10; it-1 359 ¶1)
Jèhófà rí i pé àsọtẹ́lẹ̀ tí Jékọ́bù sọ kó tó kú nímùúṣẹ (Joṣ 19:1; it-1 1200 ¶1)
Jèhófà jẹ́ káwọn èèyàn náà pinnu bí ilẹ̀ tí wọ́n máa pín fún ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan á ṣe pọ̀ tó (Joṣ 19:9; it-1 359 ¶2)
Wọ́n pín ilẹ̀ náà lọ́nà tí wọn ò fi ní máa jowú ara wọn tàbí bára wọn jà. Kí nìyẹn jẹ́ ká mọ̀ nípa bí Jèhófà ṣe máa ṣètò nǹkan nínú ayé tuntun?