May 29–June 4
2 KÍRÓNÍKÀ 28-29
Orin 54 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“O Lè Sin Jèhófà Táwọn Òbí Ẹ Ò Bá Tiẹ̀ Ṣe Bẹ́ẹ̀”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
2Kr 29:25—Báwo ni ohun tó ṣẹlẹ̀ sí Nátánì ṣe jẹ́ ká mọ àǹfààní téèyàn máa rí tó bá gba ìbáwí Jèhófà? (w12 2/15 24-25)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 2Kr 28:1-11 (th ẹ̀kọ́ 10)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Ẹni náà sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ tí wọn ò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 4)
Ìpadàbẹ̀wò: (3 min.) Àkòrí ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ ni kó o fi bẹ̀rẹ̀. Fún ẹni náà ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 19)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min.) lff ẹ̀kọ́ 10 kókó 4 (th ẹ̀kọ́ 13)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Jèhófà Ni ‘Bàbá Àwọn Ọmọ Aláìníbaba’”: (8 min.) Ìjíròrò àti fídíò.
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (7 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) lff ẹ̀kọ́ 47
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 86 àti Àdúrà