May 25-31
JẸ́NẸ́SÍSÌ 42-43
Orin 120 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Jósẹ́fù Kó Ara Ẹ̀ Níjàánu Lọ́nà Tó Lágbára”: (10 min.)
Jẹ 42:5-7—Jósẹ́fù fara balẹ̀ nígbà tó rí àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ (w15 5/1 13 ¶5; 14 ¶1)
Jẹ 42:14-17—Jósẹ́fù dán àwọn ẹ̀gbọ́n rẹ̀ wò (w15 5/1 14 ¶1)
Jẹ 42:21, 22—Àwọn ẹ̀gbọ́n Jósẹ́fù fi ẹ̀mí ìrònúpìwàdà hàn (it-2 108 ¶4)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)
Jẹ 42:22, 37—Àwọn ànímọ́ tó dáa wo ni Rúbẹ́nì fi hàn? (it-2 795)
Jẹ 43:32—Kí nìdí táwọn ará Íjíbítì fi kà á sóhun ìríra láti bá àwọn Hébérù jẹun? (w04 1/15 29 ¶2)
Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jẹ 42:1-20 (th ẹ̀kọ́ 2)
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Ìpadàbẹ̀wò Kejì—Fídíò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, lẹ́yìn náà bi wọ́n pé: Báwo ni arákùnrin yìí ṣe nasẹ̀ Ìwé Mímọ́ lọ́nà tó yẹ? Kí nìdí tí arákùnrin náà fi lo ìwé Bíbélì Kọ́ Wa? Báwo ló sì ṣe nasẹ̀ rẹ̀?
Ìpadàbẹ̀wò Kejì: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. (th ẹ̀kọ́ 15)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 34 ¶18 (th ẹ̀kọ́ 8)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
“Máa Fọkàn Yàwòrán Ohun Tó Ò Ń Kà”: (15 min.) Ìjíròrò. Ẹ wo fídíò Mú Kí Bó O Ṣe Ń Ka Bíbélì Sunwọ̀n Sí I—Àyọlò. Gba àwọn ará níyànjú láti wo fídíò náà látìbẹ̀rẹ̀ dópin.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 19 ¶15-19
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
Orin 79 àti Àdúrà