May 22-28
Jeremáyà 44-48
Orin 70 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Má Ṣe ‘Wá Àwọn Ohun Ńláńlá fún Ara Rẹ’”: (10 min.)
Jer 45:2, 3—Èrò òdì tó gba Bárúkù lọ́kàn kó wàhálà bá a (jr 104-105 ¶4-6)
Jer 45:4, 5a—Jèhófà fìfẹ́ tọ́ Bárúkù sọ́nà (jr 103 ¶2)
Jer 45:5b—Ọlọ́run dá ẹ̀mí Bárúkù sí torí pé ó gbájú mọ́ àwọn ohun tó ṣe pàtàkì jù (w16.07 8 ¶6)
Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)
Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Jer 47:1-7
MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) hf—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.
Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) hf—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) lv 199 ¶9-10—Ní ṣókí, kọ́ akẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì rẹ bó ṣe lè ṣe ìwádìí nípa ìṣòro kan tó ní.
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ẹ̀yin Ọ̀dọ́—Ẹ Má Ṣe Máa Wá Àwọn Ohun Ńláńlá fún Ara Yín: (15 min.) Ìjíròrò. Lẹ́yìn náà, jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà Àwọn Ọ̀dọ́ Béèrè Pé—Kí Ni Mo Fẹ́ Fi Ayé Mi Ṣe?—Ìrírí.
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr “Apá 4—Ìjọba Ọlọ́run Jagun Mólú—A Fi Ìdí Ìhìn Rere Múlẹ̀ Lọ́nà Òfin,” orí 13 ¶1-10
Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)
Orin 17 àti Àdúrà