March 7-13
1 SÁMÚẸ́LÌ 12-13
Orin 4 àti Àdúrà
Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN
“Téèyàn Bá Kọjá Àyè Ẹ̀, Ó Máa Kan Àbùkù”: (10 min.)
Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì: (10 min.)
1Sa 12:21—Ọ̀nà wo làwọn èèyàn náà ń gbà tẹ̀ lé “àwọn ohun asán” (tàbí, “òtúbáńtẹ́,” àlàyé ìsàlẹ̀)? (w11 7/15 13 ¶15)
Àwọn ìṣúra wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?
Bíbélì Kíkà: (4 min.) 1Sa 12:1-11 (th ẹ̀kọ́ 2)
TẸRA MỌ́ IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ
Fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Nígbà Àkọ́kọ́: Jésù—Mt 16:16. Ẹ dá fídíò náà dúró láwọn ibi tẹ́ ẹ bá ti rí ìbéèrè, kẹ́ ẹ sì jíròrò ìbéèrè náà kẹ́ ẹ tó máa wò ó lọ.
Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min.) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 1)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (5 min.) lff ẹ̀kọ́ 04 ọ̀rọ̀ ìbẹ̀rẹ̀ àti kókó 1-2 (th ẹ̀kọ́ 13)
MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI
Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe: (5 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò Ohun Tí Ètò Ọlọ́run Ti Ṣe ti oṣù March.
Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (10 min.)
Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 21 ¶13-18
Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)
Orin 26 àti Àdúrà