ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | JẸ́NẸ́SÍSÌ 22-23 “Ọlọ́run Dán Ábúráhámù Wò” TẸ̀ Ẹ̣́ “Ọlọ́run Dán Ábúráhámù Wò” 22:1, 2, 9-12, 15-18 Ẹ̀dùn ọkàn tí Ábúráhámù ní nígbà tó fẹ́ fi Ísákì rúbọ jẹ́ ká mọ bí nǹkan ṣe máa rí lára Jèhófà nígbà tó fi Jésù Kristi, Ọmọ Rẹ̀ ọ̀wọ́n rúbọ nítorí wa. (Jo 3:16) Báwo ni ọ̀rọ̀ tí Jèhófà sọ ní ẹsẹ 2 ṣe jẹ́ ká mọ bó ṣe nífẹ̀ẹ́ Jésù tó? Kí ló yẹ kí ìfẹ́ tí Jèhófà ní sún ẹ láti ṣe?—1Kọ 6:20; 1Jo 4:11 Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ “Ọlọ́run Dán Ábúráhámù Wò” ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI “Ọlọ́run Dán Ábúráhámù Wò” Yorùbá “Ọlọ́run Dán Ábúráhámù Wò” https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202020083/univ/art/202020083_univ_sqr_xl.jpg mwb20 March ojú ìwé 2