August 4-10
ÒWE 25
Orin 154 àti Àdúrà | Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)
Jésù ń bá àwọn èèyàn sọ̀rọ̀ ní sínágọ́gù tó wà ní Násárẹ́tì, ẹnu sì ń ya àwọn èèyàn bí wọ́n ṣe ń gbọ́ ọ̀rọ̀ tútù tó ń sọ
1. Àwọn Ìlànà Tó Kan Ọ̀rọ̀ Ẹnu Wa
(10 min.)
Mọ ìgbà tó yẹ kó o sọ̀rọ̀ (Owe 25:11; w15 12/15 19 ¶6-7)
Máa sọ̀rọ̀ pẹ̀lẹ́, kó o sì máa sọ̀rọ̀ lọ́nà tó ń tuni lára (Owe 25:15; w15 12/15 21 ¶15-16; wo àwòrán)
Máa sọ̀rọ̀ tó ń gbéni ró (Owe 25:25; w95 4/1 17 ¶8)
2. Àwọn Ẹ̀kọ́ Iyebíye Míì
(10 min.)
Owe 25:28—Kí ni òwe yìí túmọ̀ sí? (g19.3 6 ¶3)
Àwọn ẹ̀kọ́ iyebíye wo lo rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí tí wàá fẹ́ sọ?
3. Bíbélì Kíkà
(4 min.) Owe 25:1-17 (th ẹ̀kọ́ 10)
4. Bá A Ṣe Lè Bẹ̀rẹ̀ Ọ̀rọ̀ Wa
(3 min.) ÌWÀÁSÙ ÀÌJẸ́-BÍ-ÀṢÀ. Bá ẹnì kan tí inú ẹ̀ ò dùn sọ̀rọ̀. (lmd ẹ̀kọ́ 3 kókó 3)
5. Pa Dà Lọ
(4 min.) ÌWÀÁSÙ ILÉ-DÉ-ILÉ. Ẹni náà sọ pé òun lẹ́sìn tòun, òun ò sì lè fi í lẹ̀. (lmd ẹ̀kọ́ 8 kókó 4)
6. Àsọyé
(5 min.) yp2 105-109—Àkòrí: Kí Ló Burú Nínú Kéèyàn Máa Sọ̀rọ̀ Ẹlòmíì Lẹ́yìn? (th ẹ̀kọ́ 13)
Orin 123
7. Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ
(15 min.)
8. Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ
(30 min.) lfb ẹ̀kọ́ 6, ọ̀rọ̀ ìṣáájú fún apá 3, àti ẹ̀kọ́ 7