Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ẹ̀mí Èèyàn Ṣeyebíye Lójú Jèhófà

Ẹ̀mí Èèyàn Ṣeyebíye Lójú Jèhófà

Ó rọrùn fáwọn èèyàn láti dé ìlú ààbò (Di 19:2, 3; w17.11 14 ¶4)

Ìlú ààbò ò ní jẹ́ káwọn ọmọ Ísírẹ́lì jẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ (Di 19:10; w17.11 15 ¶9)

A lè jẹ̀bi ẹ̀jẹ̀ tá a bá ń kórìíra àwọn ará (Di 19:11-13; it-1 344)

BI ARA RẸ PÉ, ‘Báwo ni mo ṣe lè fi hàn pé ojú tí Jèhófà fi ń wo ẹ̀mí lèmi náà fi ń wò ó?’