Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

July 26–August 1

DIUTARÓNÓMÌ 19-21

July 26–August 1
  • Orin 141 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Ẹ̀mí Èèyàn Ṣeyebíye Lójú Jèhófà”: (10 min.)

  • Àwọn Ìṣúra Tẹ̀mí: (10 min.)

    • Di 21:19​—Kí nìdí tó fi jẹ́ pé ẹnubodè ìlú làwọn àgbààgbà ti ń gbọ́ ẹjọ́? (it-1 518 ¶1)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min.) Di 19:1-14 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 37

  • “Máa Rìn Láìséwu ní Ọ̀nà Rẹ”: (15 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà. Lẹ́yìn náà, bi àwọn ará ní ìbéèrè yìí: Kí nìdí tó fi yẹ ká fọwọ́ pàtàkì mú ọ̀rọ̀ ààbò? Àwọn nǹkan wo la lè ṣe ká lè dáàbò bo ara wa?

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) rr orí 11 ¶9-17

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min.)

  • Orin 108 àti Àdúrà