Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

July 6-12

Ẹ́KÍSÓDÙ 6-7

July 6-12
  • Orin 150 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Ní Báyìí, Wàá Rí Ohun Tí Màá Ṣe sí Fáráò”: (10 min.)

    • Ẹk 6:1​—Mósè máa rí “ọwọ́ agbára” Jèhófà

    • Ẹk 6:​6, 7​—Jèhófà máa gba Ísírẹ́lì sílẹ̀ (it-2 436 ¶3)

    • Ẹk 7:​4, 5​—Fáráò àtàwọn ará Íjíbítì máa mọ irú ẹni tí Jèhófà jẹ́ (it-2 436 ¶1-2)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Ẹk 6:3​—Lọ́nà wo ni Jèhófà ò fi jẹ́ kí Ábúráhámù, Ísákì àti Jékọ́bù mọ orúkọ rẹ̀? (it-1 78 ¶3-4)

    • Ẹk 7:1​—Báwo ni Mósè ṣe “dà bí Ọlọ́run” fún Fáráò, ọ̀nà wo sì ni Áárónì gbà jẹ́ “wòlíì” fún Mósè? (it-2 435 ¶5)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 6:1-15 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 45

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (15 min.)

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) jy orí 122

  • Ọ̀rọ̀ Ìparí (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

  • Orin 42 àti Àdúrà