Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

July 20-26

Ẹ́KÍSÓDÙ 10-11

July 20-26
  • Orin 65 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (1 min.)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Mósè àti Áárónì Lo Ìgboyà”: (10 min.)

    • Ẹk 10:3-6​—Mósè àti Áárónì fìgboyà kéde ìyọnu kẹjọ fún Fáráò (w09 7/15 20 ¶6)

    • Ẹk 10:24-26​—Fáráò sọ ohun tó fẹ́ káwọn ọmọ Ísírẹ́lì ṣe, àmọ́ Mósè àti Áárónì kọ̀ jálẹ̀

    • Ẹk 10:28; 11:4-8​—Mósè àti Áárónì kéde ìyọnu kẹwàá láìbẹ̀rù (it-2 436 ¶4)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (10 min.)

    • Ẹk 10:1, 2​—Ẹ̀kọ́ wo làwọn òbí lè rí kọ́ nínú ẹsẹ Bíbélì yìí? (w95 9/1 11 ¶11)

    • Ẹk 11:7​—Kí ni Jèhófà ní lọ́kàn nígbà tó sọ pé “ajá ò tiẹ̀ ní gbó àwọn ọmọ Ísírẹ́lì”? (it-1 783 ¶5)

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí nínú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí nípa Jèhófà, iṣẹ́ ìwàásù tàbí àwọn nǹkan míì?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ẹk 10:​1-15 (th ẹ̀kọ́ 10)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Fídíò Ìpadàbẹ̀wò: (5 min.) Ìjíròrò. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, lẹ́yìn náà béèrè àwọn ìbéèrè yìí: Kí lo rí kọ́ nínú bí akéde náà ṣe ṣàlàyé ọ̀rọ̀ ẹ̀ fún onílé? Kí lohun tí akéde náà lè sọ tó bá fẹ́ fún onílé ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́?

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Pe ẹni náà wá sí ìpàdé. (th ẹ̀kọ́ 8)

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ. Lẹ́yìn náà, fún un ní ọ̀kan lára àwọn ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́. (th ẹ̀kọ́ 12)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI