Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
●○○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Báwo làwọn tọkọtaya ṣe lè mú kí ìfẹ́ wọn lágbára?
Bíbélì: Ef 5:33
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo làwọn òbí ṣe lè tọ́ àwọn ọmọ wọn kí wọ́n lè jẹ́ ọmọlúwàbí?
○●○ ÌPADÀBẸ̀WÒ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Báwo làwọn òbí ṣe lè tọ́ àwọn ọmọ wọn kí wọ́n lè jẹ́ ọmọlúwàbí?
Bíbélì: Owe 22:6
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí làwọn ọmọ lè ṣe kí wọ́n má bàa kó sínú ìṣòro?
○○●ÌPADÀBẸ̀WÒ KEJÌ
Ìbéèrè: Kí làwọn ọmọ lè ṣe kí wọ́n má bàa kó sínú ìṣòro?
Bíbélì: Owe 4:5, 6
béèrè fún ìgbà míì: Báwo la ṣe lè ní ọgbọ́n tá a máa fi gbé ìgbé ayé wa lójoojúmọ́?