Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

July 31–​August 6

Ìsíkíẹ́lì 24-27

July 31–​August 6
  • Orin 81 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • Àsọtẹ́lẹ̀ Nípa Bí Ìlú Tírè Ṣe Máa Pa Run Mú Ká Fọkàn Tán Ọ̀rọ̀ Jèhófà”: (10 min.)

    • Isk 26:​3, 4​—Ó lé ní ọgọ́rùn-ún méjì ààbọ̀ [250] ọdún tí Jèhófà ti sọ tẹ́lẹ̀ pé ìlú Tírè máa pa run (si 133 ¶4)

    • Isk 26:​7-11​—Ìsíkíẹ́lì dárúkọ orílẹ̀-èdè tó máa kọ́kọ́ sàga ti ìlú Tírè, ó tún sọ orúkọ ẹni tó máa kó àwọn ọmọ ogun lọ (ce 216 ¶3)

    • Isk 26:​4, 12​—Ìsíkíẹ́lì sọ tẹ́lẹ̀ pé a ó sọ àwọn ògiri, ilé àtàwọn ilẹ̀ Tírè sínú omi (it-1 70)

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • Isk 24:​6, 12​—Kí ni ìpẹtà ìkòkò ìse-oúnjẹ dúró fún? (w07 7/1 14 ¶2)

    • Isk 24:​16, 17​—Kí nìdí tí Jèhófà fi sọ pé kí Ìsíkíẹ́lì má ṣọ̀fọ̀ nígbà tí aya rẹ̀ kú? (w88 9/15 21 ¶24)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Isk 25:​1-11

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwé àṣàrò kúkúrú èyíkéyìí​—Jẹ́ kí onílé mọ̀ pé o máa pa dà wá.

  • Ìpadàbẹ̀wò: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Ìwé àṣàrò kúkúrú èyíkéyìí​—Sọ̀rọ̀ nípa fídíò náà Báwo La Ṣe Máa Ń Ṣe Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì?, kí ẹ sì jíròrò rẹ̀ (àmọ́ ẹ má ṣe wò ó).

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì: (6 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) bh 23 ¶13-15​—Pe ẹni náà wá sí ìpàdé.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI