Nóà àti ìdílé rẹ̀ ń múra láti wọnú ọkọ̀ áàkì

ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI January 2020

Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ

Ìjíròrò tó dá lórí orúkọ Ọlọ́run, ànímọ́ ẹ̀ tó ta yọ jù lọ àti ohun tá a lè ṣe láti di ọ̀rẹ́ rẹ̀.

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Jèhófà Dá Àwọn Nǹkan Sórí Ilẹ̀ Ayé

Àwọn nǹkan wo ni Jèhófà ṣe ní ọjọ́ ìṣẹ̀dá kọ̀ọ̀kan?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Ǹjẹ́ O Lè Ṣàlàyé Ohun Tó O Gbà Gbọ́?

Ká tó lè ṣàlàyé ìdí tá a fi gbà pé Ọlọ́run ló dá ohun gbogbo fún ẹnì kan, nǹkan méjì wo la gbọ́dọ̀ ṣe?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Àbájáde Irọ́ Àkọ́kọ́

Sátánì tó jẹ́ bàbá irọ́ ṣì ń ṣi àwọn èèyàn lọ́nà.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Bá A Ṣe Lè Fi Àṣàrò Kúkúrú Bẹ̀rẹ̀ Ìjíròrò

Báwo lo ṣe lè fi àṣàrò kúkúrú bẹ̀rẹ̀ ìjíròrò lóde ẹ̀rí?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Ó Ṣe Bẹ́ẹ̀ Gẹ́lẹ́”

Kí la rí kọ́ lára Nóà tó bá kan, ìgbọràn, ìgbàgbọ́ àti fífọwọ́ pàtàkì mú iṣẹ́?

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

“Èdè Kan Ni Gbogbo Ayé Ń Sọ”

Kí ló mú káwọn èèyàn máa sọ èdè ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀? Báwo ni Ọlọ́run ṣe mú káwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ wà níṣọ̀kan láìka pé ìlú àti èdè wọn yàtọ̀ síra?

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

Túbọ̀ Já Fáfá Lẹ́nu Iṣẹ́ Rẹ

A dìídì ṣe àwọn irinṣẹ́ tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ láti ràn wá lọ́wọ́ lóde ẹ̀rí. Ṣé o mọ̀ wọ́n lò?