ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | ÌṢE 12-14 Bánábà àti Pọ́ọ̀lù Sọ Àwọn Èèyàn Tó Wà Láwọn Ọ̀nà Jíjìn Di Ọmọlẹ́yìn TẸ̀ Ẹ̣́ Bánábà àti Pọ́ọ̀lù Sọ Àwọn Èèyàn Tó Wà Láwọn Ọ̀nà Jíjìn Di Ọmọlẹ́yìn 13:12, 48; 14:1, 21, 22 Àwọn èèyàn ta ko Bánábà àti Pọ́ọ̀lù, síbẹ̀ àwọn méjèèjì ṣiṣẹ́ kára káwọn ọlọ́kàn tútù lè di Kristẹni Wọ́n wàásù fún àwọn èèyàn láìka ibi tí wọ́n ti wá sí Wọ́n gbóríyìn fún àwọn tó ṣẹ̀ṣẹ̀ di ọmọlẹ́yìn pé kí wọ́n “dúró nínú ìgbàgbọ́” Pa Dà Èyí Tó Kàn Tẹ̀ ẹ́ Fi ránṣẹ́ Fi ránṣẹ́ Bánábà àti Pọ́ọ̀lù Sọ Àwọn Èèyàn Tó Wà Láwọn Ọ̀nà Jíjìn Di Ọmọlẹ́yìn ÌWÉ ÌPÀDÉ ÌGBÉSÍ AYÉ ÀTI IṢẸ́ ÒJÍṢẸ́ ÀWA KRISTẸNI Bánábà àti Pọ́ọ̀lù Sọ Àwọn Èèyàn Tó Wà Láwọn Ọ̀nà Jíjìn Di Ọmọlẹ́yìn Yorùbá Bánábà àti Pọ́ọ̀lù Sọ Àwọn Èèyàn Tó Wà Láwọn Ọ̀nà Jíjìn Di Ọmọlẹ́yìn https://cms-imgp.jw-cdn.org/img/p/202018446/univ/art/202018446_univ_sqr_xl.jpg