Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

December 4-​10

SEFANÁYÀ 1–HÁGÁÌ 2

December 4-​10
  • Orin 151 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Múra Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Oṣù Yìí Sílẹ̀: (15 min.) Ìjíròrò tó dá lórí “Àwọn Ọ̀nà Ìgbọ́rọ̀kalẹ̀ Tá A Lè Lò.” Jẹ́ kí àwọn ará wo ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fídíò ọ̀nà ìgbọ́rọ̀kalẹ̀, kẹ́ ẹ sì jíròrò àwọn kókó pàtàkì látinú àwọn fídíò náà. Gba àwọn ará níyànjú pé kí wọ́n fún ọ̀pọ̀ èèyàn ní ìwé ìròyìn Jí! No.6 2017. Àmọ́, torí pé a fẹ́ bá àwọn èèyàn sọ̀rọ̀ ní tààràtà, a ò ní fi sí ẹnu ọ̀nà àwọn tí kò bá sí nílé.

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 30

  • Ohun Tó Ń Fẹ́ Àbójútó Nínú Ìjọ: (5 min.)

  • Èdè Mímọ́ Tó Ń Mú Kí Àlàáfíà àti Ìṣọ̀kan Túbọ̀ Máa Gbilẹ̀ (Sef 3:9): (10 min.) Ìjíròrò tó dá lórí Ilé Ìṣọ́ August 15, 2012, ojú ìwé 12, ìpínrọ̀ 4. Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà, Ọ̀tá Ni Wọ́n Tẹ́lẹ̀, Àmọ́ Ọ̀rẹ́ Ni Wọ́n Báyìí.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) kr orí 22 ¶8-16

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3min.)

  • Orin 136 àti Àdúrà