Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | SEKARÁYÀ 1-8

“Di Aṣọ Ọkùnrin Tó Jẹ́ Júù Mú”

“Di Aṣọ Ọkùnrin Tó Jẹ́ Júù Mú”

8:20-23

Ọkùnrin mẹ́wàá láti inú gbogbo èdè àwọn orílẹ̀-èdè yóò dì í mú, bẹ́ẹ̀ ni, ní ti tòótọ́, wọn yóò di ibi gbígbárìyẹ̀ lára aṣọ ọkùnrin kan tí ó jẹ́ Júù mú, pé: “Àwa yóò bá yín lọ.” Ní àwọn ọjọ́ ìkẹyìn yìí, àwọn èèyàn láti gbogbo orílẹ̀-èdè ń rọ́ wá jọ́sìn Jèhófà ní ìfẹ̀gbẹ́kẹ̀gbẹ́ pẹ̀lú àwọn ẹni àmì òróró

Àwọn ọ̀nà wo ni àwọn àgùntàn mìíràn ń gbà ṣètìlẹ́yìn fún àwọn ẹni àmì òróró lónìí?

  • Wọ́n ń fi ìtara ṣe iṣẹ́ ìwàásù

  • Tọkàntọkàn ni wọ́n ń fi owó ṣètìlẹ́yìn fún iṣẹ́ náà