Privacy Settings

To provide you with the best possible experience, we use cookies and similar technologies. Some cookies are necessary to make our website work and cannot be refused. You can accept or decline the use of additional cookies, which we use only to improve your experience. None of this data will ever be sold or used for marketing. To learn more, read the Global Policy on Use of Cookies and Similar Technologies. You can customize your settings at any time by going to Privacy Settings.

Lọ wo ohun tó wà nínú rẹ̀

Lọ wo àwọn ohun tó wà

Àkọsílẹ̀ Ìhìn Rere Jòhánù

Orí

1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 16 17 18 19 20 21

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí

  • 1

    • Ọ̀rọ̀ náà di ẹlẹ́ran ara (1-18)

    • Jòhánù Arinibọmi jẹ́rìí (19-28)

    • Jésù ni Ọ̀dọ́ Àgùntàn Ọlọ́run (29-34)

    • Àwọn ọmọ ẹ̀yìn tí Jésù kọ́kọ́ yàn (35-42)

    • Fílípì àti Nàtáníẹ́lì (43-51)

  • 2

    • Ìgbéyàwó ní Kánà; omi di wáìnì (1-12)

    • Jésù fọ tẹ́ńpìlì mọ́ (13-22)

    • Jésù mọ ohun tó wà nínú èèyàn (23-25)

  • 3

    • Jésù àti Nikodémù (1-21)

      • Àtúnbí (3-8)

      • Ọlọ́run nífẹ̀ẹ́ ayé (16)

    • Ẹ̀rí tí Jòhánù jẹ́ gbẹ̀yìn nípa Jésù (22-30)

    • Ẹni tó wá láti òkè (31-36)

  • 4

    • Jésù àti obìnrin ará Samáríà (1-38)

      • Jọ́sìn Ọlọ́run “ní ẹ̀mí àti òtítọ́” (23, 24)

    • Ọ̀pọ̀ àwọn ará Samáríà gba Jésù gbọ́ (39-42)

    • Jésù wo ọmọkùnrin òṣìṣẹ́ ọba kan sàn (43-54)

  • 5

    • Ó wo ọkùnrin kan sàn ní Bẹtisátà (1-18)

    • Jésù gba àṣẹ lọ́dọ̀ Baba rẹ̀ (19-24)

    • Àwọn òkú máa gbọ́ ohùn Jésù (25-30)

    • Àwọn ẹ̀rí nípa Jésù (31-47)

  • 6

    • Jésù bọ́ 5,000 èèyàn (1-15)

    • Jésù rìn lórí omi (16-21)

    • Jésù ni “oúnjẹ ìyè” (22-59)

    • Ọ̀pọ̀ èèyàn kọsẹ̀ nítorí ọ̀rọ̀ Jésù (60-71)

  • 7

    • Jésù lọ síbi Àjọyọ̀ Àwọn Àgọ́ Ìjọsìn (1-13)

    • Jésù ń kọ́ni níbi àjọyọ̀ náà (14-24)

    • Oríṣiríṣi ohun tí àwọn èèyàn ń sọ nípa Kristi (25-52)

  • 8

    • Baba ń jẹ́rìí nípa Jésù (12-30)

      • Jésù ni “ìmọ́lẹ̀ ayé” (12)

    • Àwọn ọmọ Ábúráhámù (31-41)

      • ‘Òtítọ́ máa sọ yín di òmìnira’ (32)

    • Àwọn ọmọ Èṣù (42-47)

    • Jésù àti Ábúráhámù (48-59)

  • 9

    • Jésù wo ọkùnrin tí wọ́n bí ní afọ́jú sàn (1-12)

    • Àwọn Farisí ń bi ọkùnrin tó wò sàn ní ìbéèrè (13-34)

    • Àwọn Farisí fọ́jú (35-41)

  • 10

    • Olùṣọ́ àgùntàn àti ọgbà àgùntàn (1-21)

      • Jésù ni olùṣọ́ àgùntàn àtàtà (11-15)

      • “Mo ní àwọn àgùntàn mìíràn” (16)

    • Àwọn Júù ta ko Jésù níbi Àjọyọ̀ Ìyàsímímọ́ (22-39)

      • Ọ̀pọ̀ àwọn Júù ò gbà gbọ́ (24-26)

      • “Àwọn àgùntàn mi máa ń fetí sí ohùn mi” (27)

      • Ọmọ wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Baba (30, 38)

    • Ọ̀pọ̀ àwọn tó wà ní òdìkejì Jọ́dánì gbà gbọ́ (40-42)

  • 11

    • Ikú Lásárù (1-16)

    • Jésù tu Màtá àti Màríà nínú (17-37)

    • Jésù jí Lásárù dìde (38-44)

    • Wọ́n gbìmọ̀ láti pa Jésù (45-57)

  • 12

    • Màríà da òróró sí ẹsẹ̀ Jésù (1-11)

    • Jésù gun ọmọ kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ wọnú ìlú (12-19)

    • Jésù sọ tẹ́lẹ̀ nípa ikú rẹ̀ (20-37)

    • Àìnígbàgbọ́ àwọn Júù mú àsọtẹ́lẹ̀ ṣẹ (38-43)

    • Jésù wá gba ayé là (44-50)

  • 13

    • Jésù fọ ẹsẹ̀ àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ (1-20)

    • Jésù fi hàn pé Júdásì ló máa da òun (21-30)

    • Àṣẹ tuntun (31-35)

      • “Tí ìfẹ́ bá wà láàárín yín” (35)

    • Ó sọ tẹ́lẹ̀ pé Pétérù máa sẹ́ òun (36-38)

  • 14

    • Nípasẹ̀ Jésù nìkan la fi lè dé ọ̀dọ̀ Baba (1-14)

      • ‘Èmi ni ọ̀nà, òtítọ́ àti ìyè’ (6)

    • Jésù ní òun máa rán ẹ̀mí mímọ́ (15-31)

      • “Baba tóbi jù mí lọ” (28)

  • 15

    • Àpèjúwe àjàrà tòótọ́ (1-10)

    • Kristi pàṣẹ pé kí wọ́n ní irú ìfẹ́ tí òun ní (11-17)

      • ‘Kò sí ìfẹ́ tó ju èyí lọ’ (13)

    • Ayé kórìíra àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jésù (18-27)

  • 16

    • Wọ́n lè pa àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jésù (1-4a)

    • Iṣẹ́ tí ẹ̀mí mímọ́ máa ṣe (4b-16)

    • Ìbànújẹ́ àwọn ọmọ ẹ̀yìn máa di ayọ̀ (17-24)

    • Jésù ti ṣẹ́gun ayé (25-33)

  • 17

    • Jésù gbàdúrà tó kẹ́yìn pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ (1-26)

      • Tí a bá wá mọ Ọlọ́run, ó máa yọrí sí ìyè àìnípẹ̀kun (3)

      • Àwọn Kristẹni kì í ṣe apá kan ayé (14-16)

      • “Òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ rẹ” (17)

      • “Mo ti jẹ́ kí wọ́n mọ orúkọ rẹ” (26)

  • 18

    • Júdásì da Jésù (1-9)

    • Pétérù lo idà (10, 11)

    • Wọ́n mú Jésù lọ sọ́dọ̀ Ánásì (12-14)

    • Ìgbà àkọ́kọ́ tí Pétérù sẹ́ (15-18)

    • Jésù dé iwájú Ánásì (19-24)

    • Pétérù sẹ́ lẹ́ẹ̀kejì àti lẹ́ẹ̀kẹta (25-27)

    • Jésù dé iwájú Pílátù (28-40)

      • “Ìjọba mi kì í ṣe apá kan ayé yìí” (36)

  • 19

    • Wọ́n na Jésù, wọ́n sì fi ṣe yẹ̀yẹ́ (1-7)

    • Pílátù tún bi Jésù léèrè ọ̀rọ̀ (8-16a)

    • Wọ́n kan Jésù mọ́ òpó igi ní Gọ́gọ́tà (16b-24)

    • Jésù ṣètò bí wọ́n ṣe máa bójú tó ìyá rẹ̀ (25-27)

    • Ikú Jésù (28-37)

    • Wọ́n sìnkú Jésù (38-42)

  • 20

    • Ibojì ṣófo (1-10)

    • Jésù fara han Màríà Magidalénì (11-18)

    • Jésù fara han àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ (19-23)

    • Tọ́másì ṣiyèméjì, àmọ́ ó pa dà dá a lójú (24-29)

    • Ìdí tí wọ́n fi kọ àkájọ ìwé yìí (30, 31)

  • 21

    • Jésù fara han àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ (1-14)

    • Pétérù fi dá Jésù lójú pé òun nífẹ̀ẹ́ rẹ̀ (15-19)

      • “Máa bọ́ àwọn àgùntàn mi kéékèèké” (17)

    • Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí ọmọ ẹ̀yìn tí Jésù nífẹ̀ẹ́ (20-23)

    • Ọ̀rọ̀ ìparí (24, 25)