Sáàmù 133:1-3

  • Wọ́n ń gbé pọ̀ ní ìṣọ̀kan

    • Bí òróró lórí Áárónì (2)

    • Bí ìrì Hámónì (3)

Orin Ìgòkè. Ti Dáfídì. 133  Wò ó! Ó mà dára o, ó mà dùn oPé kí àwọn ará máa gbé pọ̀ ní ìṣọ̀kan!+  Ó dà bí òróró dáradára tí a dà sí orí,+Tó ń ṣàn sára irùngbọ̀n,Irùngbọ̀n Áárónì,+Tó sì ń ṣàn sí ọrùn aṣọ rẹ̀.  Ó dà bí ìrì Hámónì+Tó ń sẹ̀ sórí àwọn òkè Síónì.+ Ibẹ̀ ni Jèhófà ti pàṣẹ ìbùkún rẹ̀,Ìyè àìnípẹ̀kun.

Àlàyé Ìsàlẹ̀ Ìwé